°Ç¸ç³Ô¹Ï

Skip to main content
Guidance

Notice of rights and entitlements Yoruba (PACE Code C) (accessible version)

Updated 27 January 2020

Ranti awá»n ẹtá» rẹ ni igba ti o wa ni atimá»le

Awá»n ẹtá» ti a Pese fun á» ni yi a se onigbá»wá» fun labẹ ofin ni orilẹ-ede England ati Wales ati pe a gba pẹlu Àjá» lori ẹtá» rẹ si iwifun ninu ilana iwadi ti iwa buburu.

Awá»n ẹtá» rẹ ni ile iṣẹ agá» á»lá»pa ni a ká» si ibi

A si tun ni awá»n alaye ni ẹkurẹrẹ ni ori ẹsẹ kinni (1) titidi ori ẹsẹ ká»kanla (11).

Ẹkurẹrẹ alaye wa ninu Iwe Ilana Ã’fin ti á»lá»pa C.

  1. Sá» fun á»lá»pa ti o ba fẹ ki agbẹjá»ro kan o ran á» lá»wá» ni igba ti o ba wa ni agá» á»lá»pa. Eyii jẹ á»fẹ.

  2. Sá» fun á»lá»pa ti o ba ni ẹnikẹni ti o fẹ sá» ibi ti o wa fún. Eyii jẹ á»fẹ.

  3. Sá» fun á»lá»pa ti o ba fẹ wo awá»n ofin wá»n- eyi jẹ Ilana Ofin Ise wá»n.

  4. Sá» fun á»lá»pa ti o ba nilo itá»ju ara. Sá» fun á»lá»pa ti ara rẹ ko ba ya tabi ti o ba fi ara sèèse. Ọfẹ ni ile iwosan.

  5. Ti a ba bi o ni ibeere nipa awá»n ẹsẹ kan ti a fura si, o ko nilo lati sá» ohunkohun. Ẹwẹ, o le se akoba fun aroye rẹ ti o ko ba dahun si ibeere ohun kan eyiti o nilo t’oba ya ni ile ẹjá». Ohun k’ohun ti o ba sá» ni a o lo gẹgẹbi ẹri fun á».

  6. Ọlá»pa ni lati se alaye fun á» lori ẹsẹ ti a ro pe o da ati idi ti a fi mu á» ti a si fi á» si inu atimá»le.

  7. Ọloá»pa ni lati jẹ ki iwá» tabi agbẹjá»ro rẹ ri awá»n iwe aká»silẹ ati ipamá» fun idi ti a fi mu á» ti o si wa ni àtìmá»Ì lé àti nipa asiko rẹ ni agá» á»lá»pa.

  8. Ti o ba nilo atumá» ede, á»lá»pa naa gbá»dá» pese á»kan fun á». O le ni awá»n iwe ti a tumá» pẹlu. Eyii jẹ á»fẹ.

  9. Sá» fun á»lá»pa ti o kii ba se á»má» orilẹ-ede Britain ti o si fẹ kan si ajá» tabi aá¹£oju orilẹ-ede rẹ abi o fẹ ki a sá» fun wá»n pe o wa ninu atimá»le. Eyii jẹ á»fẹ.

  10. Ọlá»pa ni lati sá» iye igba ti o ma fi wa ninu atimá»le fun á».

  11. Ti a ba fi ẹsun kan á» ti ẹjá» rẹ si de ile ẹjá», iwá» tabi agbẹjá»ro rẹ ni ẹtá» lati ri iwe ipẹjá» ki igbẹjá» to bẹrẹ.

Ti awon ẹtá» wá»nyi ko ba da á» l’oju, , sá» fun á»lá»pa alamojuto naa

Wo awá»n oju-iwe akojá» naa fun awá»n alaye ni ẹkunrẹrẹ nipa bi á»lá»pa se yẹ ki o se abojuto ati itá»ju rẹ.

Ẹya Akiyesi awá»n Ẹtá» ati Ajẹmá»nu ni ipa lati 21 August 2019 (ojo kanle logun, osu kejo odun 2019)

Já»wá» fi iwifun yi pamá» ki o si ka-a ni kiakia. Yo ran á» lá»wá» lati se awá»n ipinnu nigba ti o wa ni agá» á»lá»pa.

1. Gbigba agbẹjá»ro lati ran á» lá»wá».

  • Agbẹjá»ro le ran á» lá»wá» o si le fun á» ni imá»ran nipa ofin.
  • Bíbèèrè lati sá»rá» pẹlu agbẹjá»ro ko jẹki o ri bii wipe o ti se ohun ki ko bojumu.
  • Olopa Alatimá»le gbá»dá» beere lá»wá» rẹ bi o ba fẹ imá»ran agbẹjá»ro. Eyii jẹ á»fẹ.
  • Awá»n á»lá»pa gbá»dá» jẹki o ba agbẹjá»ro sá»rá» ni igbakugba, á»san tabi asaalẹ, nigbati o bawa ni agá» á»lá»pa.
  • Bi o ba beere fun imá»ran ofin, a ki nsaba gba ki awá»n á»lá»pa beere ibeere kankan lá»woá» rẹ titi ti o fi ni anfaani lati ba agbẹjoá»ro kan sá»rá». Nigbati awá»n á»lá»pa ba beere awá»n ibeere lá»wá» rẹ, o le beere fun agbẹjá»ro lati wa ninu yara pẹlu rẹ.
  • Bi o ba ti sá»fun awá»n á»lá»pa wipe o ko fá» imá»ran ofin sugbon o wa yi á»kan rẹ pada, sá» fun á»lá»pa alatimá»le ti yoo wa ran á» lá»wá» lati kan si agbẹjá»ro kan.
  • Bi agbẹjá»ro kan ko ba yá»ju tabi kan si á» ni agá» á»lá»pa, tabi o nilo lati ba agbẹjá»ro kan sá»rá» lẹẹkansi, beere lá»wá» awá»n á»lá»pa lati kan si wá»n lẹẹkansi.

Imá»ran ofin á»fẹ nipa awá»n ohun ti ko l’ewu pupá»:

  • Ninu awon ẹjá» ká»á»kan ti ko l’ewu pupá», awá»n aká»á¹£áº¹má»á¹£áº¹ oludamá»ran lati Iṣẹ Aabo Arufin (CDS) taara nikan lo le gbani n’ imá»ran ofin á»fẹ lori ẹrá» ibaraẹnisá»rá» ayafi ti agbẹjá»ro ba wa lati agá» á»lá»pa, bii:
    • Awá»n á»loá»pa fẹ beere awá»n ibeere nipa ẹsẹ kan tabi se eto idanimo eleri.
    • o nilo iranlá»wá» lati á»dỠ“agbalagba ti o yẹâ€. Wo “Awá»n eniyan ti o nilo iranlá»wá»â€.
    • o kole soro lori ẹrá» ibaraẹnisá»rá», tabi
    • o fi ẹsun ihuwasi odi lile kan awá»n á»lá»pa.

Igbati igbani n’ imá»ran ofin á»fẹ lori ẹrá» ibaraẹnisá»rá» ki se fun Iṣẹ Aabo Arufin (CDS) Taara nikan:

  • O le beere lati ba agbẹjá»ro kan ti o má» sá»rá» o ko si nilo lati sanwo ti wá»n ba se ise iranwá» agbẹjá»ro. Bi o ko ba má» agbẹjá»ro kankan tabi a ko le kan si agbẹjá»ro ti o má», o le ba agbẹjá»ro ti o wa lẹnu iṣẹ sá»rá». Eyii jẹ á»fẹ.

  • Agbẹjá»ro ti o wa lẹnu iṣẹ koni ohunkohun se pẹlu awá»n á»lá»pa.

Lati s’eto fun imá»ran ofin á»fẹ:

  • Awá»n á»lá»pa yo kan si Ibi Ipe Agbẹjá»ro Aabo (DSCC). DSCC naa yo s’eto fun lati gba imoran ofin, lati á»dá» CDS Taara, lati á»dá» agbẹjá»ro kan ti o ti beere fun tabi lati á»dá» Agbẹjá»ro ti o wa lenu iṣẹ naa.

  • DSCC ati CDS Taara naa jẹ awá»n iṣẹ ara-ẹni to nseto imoran ofin á»fẹ ti ko si ni ohunkohun se pẹlu awá»n á»lá»pa.

Bi o ba fẹ sanwo fun imá»ran ofin fun’ra rẹ:

  • Ni gbogbo igba o le san owo fun imá»ran ofin ti o ba fẹ bẹ.
  • Nigbati igbani n’ imá»ran ofin á»fẹ lori ẹrá» ibaraẹnisá»rá» wa fun CDS Taara nikan o si tun le ba agbẹjá»ro ti o fẹ sá»rá» lori ẹrá» ibaraẹnisá»rá» bi o ba fẹ bẹ, sugbon iranwá» ofin ko ni san’wo fun wá»won si le ni ki o sanwo fun wá»n. DSCC naa yo ba á» kan si agbejoro rẹ.
  • O l’ẹtá» lati ba agbẹjá»ro ti o yan sá»rá» ni ká»ká» lori ẹrá» ibaraẹnisá»rá» tabi wá»n le pinnu lati wa ri á» ni agá» á»lá»pa.
  • Bi agbẹjá»ro ti o fẹ ko ba see kan si, awá»n á»lá»pa si le pe DSCC naa lati s’eto imá»ran ofin á»fẹ lati á»dá» Agbẹjá»ro ti o wa lẹnu iṣẹ.

2. Sisá» fun ẹnikan wipe o wa ni agá» á»lá»pa

  • O le beere pe ki awá»n á»lá»pa ba á» kan si ẹnikan ti o yẹ lati má» pe o wa ni agá» á»lá»pa. Eyii jẹ á»fẹ.
  • Wá»n yo ba á» kan si ẹnikan ni kiakia.

3. Wiwo awá»n Ofin Ise

  • Awon Ofin Ise jẹ awá»n ofin ti yo sá» ohun ti awá»n á»lá»pa lese ati ohun ti wá»n ko le se nigbati o ba wa ni agá» á»lá»pa.
  • Awá»n á»lá»pa yo jẹki o ka Awon Ofin Ise naa, sugbon o ko le s’eyi ti yo ba da awá»n á»lá»pa duro nipa wiwadi boya o ti rufin.
  • Bi o ba fe ka Awá»n Ofin Ise naa, so fun Ọlá»pa Alatimá»le naa

4. Gbigba iranwỠiwosan ti ara rẹ ba ya tabi ti o ba sese

  • Sá» fun awá»n á»lá»pa bi ara rẹ ko ba ya tabi nilo oogun tabi ti o ba sese. Wá»n yo pe dokita tabi ná»á»si tabi aká»á¹£áº¹má»á¹£áº¹ iwosan miiran á»feẹ si ni.
  • A le gba o laaye lati lo oogun tirẹ, sugbá»n awá»n á»lá»pa yo ká»ká» yẹwo naa. Ná»á»si kan yo ká»ká» ri á» na, sugbá»n awá»n á»lá»pa yo ransẹ pe dokita kan bi o ba nilo á»kan. O le beere lati ri dokita miiran, sugbá»n o le ni lati sanwo fun eyi.

5. ẸtỠlati wa ni idakẹ

Ti a ba beere ibeere lá»wá» rẹ nipa ẹsẹ ti a fura si, o ko nilo lati sá» ohunkohun.

Ẹwẹ, o le se akoba fun aroye rẹ ti o ko ba dahun si ibeere ohun kan eyiti o nilo t’oba ya ni ile ẹjá».

Ohun k’ohun ti o ba sá» ni a o lo gẹgẹbi ẹri fun á».

6. Mimá» nipa ẹsẹ ti a fura si pe o sẹ ati mimá» idi ti a fii mu o ati ti á» má»â€™le

  • Ọlá»pa gbá»dá» sá» nipa iru ẹsẹ ti wá»n ro pe o ti da.. Eyi pẹlu igba ati ibi ti wá»n ro pe o ti sẹ.
  • Ọlá»pa gbá»dá» sá» idi ti woá»n fi ro pe o sẹ ẹsẹ naa fun á» ati idi ti wá»n fi gbagbá» pe o yẹ ki awá»n mu á».
  • Ni agá» á»lá»pa, á»lá»pa naa gbá»dá» sá» idi ti wá»n fi gbagbá» pe o yẹ fun atimá»se fun á».
  • Ki a to bi á» ni ibeere kankan nipa ẹsẹ kankan, á»lá»pa ni lati fun iwá» ati agbẹjá»ro rẹ ni iwifun ti o to nipa ohun ti á»lá»pa ro pe o se ki o le ba gba ara rẹ silẹ, sugbá»n kii se akoko ti yoo pa iwadi á»lá»pa naa lara.
  • Eyi wa fun awá»n ẹsẹ miran ti awá»n á»lá»pa ro pe o se.

7. Wiwo awá»n iwe aká»silẹ ati ipamá» nipa mímú ati itimá»le rẹ.

  • Ni igba ti o ba wa ni atimá»le ni agá» á»lá»pa, á»lá»pa gbá»dá»:
    • Aká»silẹ ninu iwe ipamá» rẹ, idi ti wá»n fi mu á» ati idi ti wá»n fi gbagbá» pe o ye ki o wa ni atimá»le.
    • Je ki iwá» ati agbẹjá»ro rẹ wo iwe aká»silẹ rẹ. Ọlá»pa ahamá» yoo s’eto eyi.
  • Eyi wa fun awá»n ẹsẹ miran ti olopa ro pe o sẹ.
  • Ọlá»pa gbá»dá» gba ki iwá» tabi agbẹjá»ro rẹ ni anfaani si awá»n iwe ati ohun ti o yẹ lilo lati gbogun ti ofin ti o sokun fa mimu ati titi á» má»le.

8. Gbigba atumá» ede ati itumá» awá»n iwe ká»á»kan lati ran á» lá»wá»

  • Ti o ko ba le sá» tabi gbá» ede Gẹẹsi, awá»n á»lá»pa yo s’eto fun enikan ti o nsá» ede rẹ lati ran á» lá»wá». Eyi jẹ á»fẹ.
  • Bi o ba jẹ odi tabi ni isoro lati sá»rá», awá»n á»lá»pa yo s’eto fun Atumá» Ede Gẹẹsi Ilu Britian lati ran á» lá»wá». Eyi jẹ á»fẹ.
  • Ti o ko ba gbá» tabi sá» ede Gẹẹsi,, á»lá»pa yo ba á» gba atumá» ede lati sá» idi ti o fi wa ni atimá»le. Eyi gbá»dá» jẹ sise nigbogbo igba ti a ba se ipinnu lati fi á» si ahamá».
  • Lẹyin ipinnu ká»á»kan lati fi á» si ahamá» ati leyin ti fi ẹsun ẹsẹ kan á», á»lá»pa gbá»dá» fun á» ni iwe aká»silẹ idi atimá»le ati ẹsun ẹsẹ rẹ ni ede rẹ, ayafi ti idi pataki lati ma se ba wa. Awá»n ni:
    • Ti o ba pinu pe o ko nilo aká»silẹ naa lati fi gba ararẹ silẹ nitori pe o ni oye kikun nipa ohun ti o nsẹlẹ ati atunbá»tan aini iwe aká»silẹyi ti o si ti ni anfaani lati bi agbẹjá»ro fun iranlá»wá» ati se ipinnu. O gbá»dá» f’á»wá» si nipa iwe kiká». -T’oba jẹ nipa itumá» ede á»lá»rá» tabi akojá» nipa atumá» ede dipo kiká» itumá» ede ni yoo to fun á» lati gba ara rẹ silẹ ti o si ni oye ohun to nsẹlẹ. Ọlá»pa alahamá» gbá»dá» f’á»wá» si eyi.
  • Nigbati awá»n á»lá»pa ba beere ibeere lá»wá» rẹ ti wá»n ko si gba ohun silẹ, atumá» ede naa yoo ka awá»n ibeere ati idahun rẹ silẹ ni ede tire. O ni anfaani lati yẹ eyi wo ki o to f’á»wá» sii gẹgẹbi aká»silẹ to yẹ.
  • Bi o ba fẹ sá» gbolohun á»rá» kan fun awá»n á»lá»pa, atumá» ede naa yoo se ẹda gbolohun naa ni ede tirẹ fun á» lati yẹẹwo ki o si f’á»wá» pe o tá».
  • O si tun l’ẹtá» si itumá» ede akiyesi yi. Ti ko ba si itumá» ede l’ará»wá»to, o nilo lati gba iwifun naa nipasẹ atumá» ede kan ki o si fun á» ni itumá» ede naa lai fi akoko s’ofo.

9. Kikan si ajỠtabi aṣoju orilẹ-ede rẹ

Ti o kii ba se á»má» orilẹ-ede Britain, o le sá» fun awá»n á»lá»pa wipe o fẹ kan si Ajá» Agba, Ajá» Asoju tabi Igbimá» Asoju Orilẹ-ede rẹ lati sá» ibi ti o wa fun wá»n ati idi ti o fi wa ni agá» á»lá»pa. Wá»n tun le bẹ o wo ni iká»ká» tabi s’eto fun agbẹjá»ro lati ri á».

10. Igba wo l’ole wa ni atimá»le da

  • O le wa ni atimá»le fun wakati 24 lai gbe á» lá» si’le ẹjá». Eyi le pẹayafi ti adajá» tabi adajá» agba ni ile-ẹjá» giga ba da ẹjá» naa ti Ọga Ọlá»pa tabi ile-ẹjá» si gba laaye lati sẹlẹ. Lẹyin wakati 36, ile-ẹjá» nikan l’ole gba awá»n á»lá»pa laaye lati ti á» má»â€™le fun akoko die si lai pe á» l’ẹjá».
  • Lati igba de igba á»ga á»lá»pa kan gbá»do ma wo ẹjá» rẹ lati ri daju pe a o da á» duro si agá» á»lá»pa. Eyi ni a npe ni atunyẹwo, á»lá»pa naa si ni á»lá»pa ayẹwo. Afi ti o ko ba si ni ipo ilera, o ni ẹtá» lati le sá»rá» si ipinnu yi nipa kiká» iwe tabi sisá» fun á»lá»pa ayẹwo tabi lori ala amuhunmaworan kan. Agbẹjá»ro rẹ naa ni ẹtá» si á»rá» sisá» lori eyi, dipo rẹ.
  • Ti á»lá»pa ayẹwo ko ba fi á» silẹ, a ni lati má» b’ose jẹ ati idi to wa l’aká»silẹ ninu aká»silẹ ahamá» rẹ.
  • Ti atimá»le rẹ ko ba nilo, a gbá»dá» fi á» silẹ. Ti awá»n á»lá»pa ba sá» fun á» pe awá»n fẹ tẹsiwaju lati se iwaadi ẹsun naa, a o fi á» silẹ boya nipa gbigba beli tabi aigba beli. T’o ba jẹ beli, wá»n gbá»dá» fun á» ni iwe afiyesi lati sá» fun á» pe o gbá»dá» pada si agá» á»lá»pa ati nipa ohunkohun to ba rá» má» beli rẹ.
  • Ti awá»n á»lá»pa ba fẹ beere pe ki ile-ẹjá» fi kun akoko itimá»le rẹ:
    • O ni lati wa ni ile ẹjá» fun ijẹjá» ayafi ti eto ala amohunmaworan ba wa, ki o le ba ri ati gbá» awá»n eniyan ninu ile ẹjá» awá»n naa yoo si le ri ati gbá» á».
    • A o le s’eto ala amohunmaworan ayafi ti á»lá»pa alabojuto sá» pe o bojumu, agbẹjá»ro kan ba ti gba á» nimá»ran nipa ilo rẹ ati ti iwá» naa ba f’á»wá» si.
    • O gbá»dá» gba ẹda iwifun naa ti o sá» fun ile-ẹjá» nipa ẹri ati idi ti á»lá»pa se fẹ ko wa ni ahamá».
    • O ni ẹtá» lati ni agbẹjá»ro kan pẹlu rẹ fun ijẹjá» ni ile ẹjá».
    • A o gba á»lá»pa laye lati fi á» si ahamá» ti ile ẹjá» ba gbagbá» pe o yẹ ati wipe ki awá»n á»lá»pa nse iwadi á»rá» daadaa lai fi akoko s’ofo.
  • Ti awá»n á»lá»pa ba ni ẹri to daju lati fi ran á» lá» si ile ẹjá», a le pe á» l’ẹjá» ni agá» á»lá»pa tabi nipa ifiransẹ, pe ki o fi oju ba ile ẹjá» fun idajá».

11. Anfaani si ẹri ti á»rá» rẹ ba lá» si ile ẹjá»

Ti a ba fi ẹsun ẹsẹ kan kàn á», iwá» tabi agbẹjá»ro rẹ ni lati ri ẹri ti a fi tako á» ati ẹri ti o le ran á» lá»wá» lati gba ara rẹ silẹ.. Eyi gbá»dá» waye ki igbẹjá» rẹ to bẹrẹ. Ọlá»pa ati awon Ilana Ise Idajo gbá»dá» s’eto eyi ki wá»n si pese anfaani si awá»n iwe ti o yẹ.

Awá»n ohun miiran lati má» nipa wiwa ni Agá» á»lá»pa

Bi o se yẹ ki a tá»ju ati mojuto á»

Awá»n aká»silẹ yii sá» fun á» nipa ohun ti o le reti nigbati a ba fi á» si agá» á»lá»pa. Lati wadi sii, beere alti ri Awon Ise Ofin. Eyi pẹlu akojá» ibi ti o ti le ri iwifun sii nipa á»ká»á»kan nipa awá»n ohun wá»nyi. Beere lá»wá» á»lá»pa ahamá» bi o ba ni ibeere Kankan.

Awá»n eniyan ti o nilo iranlá»wá»

  • Bi o ko ba ti pe omo odun mejidilogun (18) tabi ti o ni ipalara, fun apẹẹrẹ ti o ni isoro ẹká» tabi ailera á»pá»lá», o ni ẹtá» si ẹnikan lati wa pẹlu rẹ nigbati awá»n á»lá»pa ba nse ohun kan. Ẹni yi ni “agba to yẹ†wá»n yo si gba ẹda akiyesi yi.
  • Agba rẹ kan yoo ran á» lá»wá» lati má» ohun to nsẹlẹ yoo si ba á» s’amojuto awá»n ipinnu rẹ. O gbá»dá» wa pẹlu rẹ nigbati awá»n á»lá»pa ba nsá» fun á» nipa awá»n ẹỠrẹ ati idi ti a fi wa ni agá» á»lá»pa. O tun gbá»dá» wa pẹlu rẹ nigbati á»lá»pa ba nka awá»n ikilá» á»lá»pa fun á».
  • Agba rẹ to yẹ naa le beere agbẹjá»ro fun á».
  • O le ba agbẹjá»ro rẹ sá»rá» laisi agba rẹ to yẹ ninu yara naa bi o ba fẹ.
  • Awá»n á»lá»pa naa le nilo lati se ohun kan ninu awá»n ohun akojá» to wa nisale yi nigbati o ba wa ni agá» olá»pa. Ayafi ti awá»n akanse idi ba wa, agba rẹ ti o yẹ gbá»dá» wa pẹlu rẹ fun gbogbo akoko naa bi awá»n á»lá»pa ba se ohunkohun ninu awá»n wá»nyi:
    • Fi á»rá» wa á» l’ẹnu wo tabi beere pe ki f’á»wá» si iwe kiká» tabi awá»n aká»silẹ á»lá»pa.
    • Bá» ju asá» ita rẹ lá» lati yẹ á» wo.
    • Tẹka, ya aworan tabi ayẹwo idanimá» (DNA) tabi awá»n ayẹwo miiran.
    • Se ohunkohun ti o niise pẹlu eto ida ẹlẹri má».
  • A gbá»dá» fun agba rẹ ni aaye lati wa lará»wá»to rẹ tabi lori ẹrá» ibataẹnisá»rá» lati ran á» lá»wá», nigbati awá»n á»lá»pa ba nse ayẹwo ẹsun rẹ lati rii boya o ma wa ni atimá»le sii.
  • Ti agba rẹ ba ri aaye, wá»n gbá»do wa nibẹ nigbati á»lá»pa naa ba nfi ẹsun kan á».

Gbigba alaye nipa akoko rẹ ni agá» á»lá»pa

  • Gbogbo ohun ti o ba sẹlẹ si á» nigbati o ba wa ni agá» á»lá»pa ni a ka silẹ Eyi ni a npe ni Akasilẹ Ahamá».

  • Nigbati o ba kuro ni agá» á»lá»pa naa, iwá», agbẹjá»ro rẹ tabi agba rẹ ti o yẹ le beere fun ẹda Akasilẹ Ahamá». Awá»n á»lá»pa ni lati fun á» ni ẹda Akasilẹ Ahamá» rẹ ni kopẹkopẹ.

  • O le beere lá»wá» awá»n á»lá»pa fun ẹda Akasilẹ Ahamá» rẹ titi di osu 12 lẹyin ti o ti kuro ni agá» á»lá»pa.

Biba awá»n eniyan sá»rá»

  • Pẹlu biba agbẹjá»ro sá»rá» ati sisá» fun ẹnikan nipa atimá»le rẹ a o ma tun gba á» laaye lati se ipe kan.
  • Beere lá»wá» awá»n á»lá»pa bi o ba fẹ pe.
  • O si tun le beere fun kalamu ati iwe pelebe.
  • O le ni awá»n alejo sugbá»n á»lá»pa ahamá» le ká» lati gba iyẹn.

Ile Ẹwá»n rẹ

  • Bi o ba seese o yẹ ki o da wa ninu ile ẹwá»n.
  • O yẹ ki o má»Ì, lá»wá»á»rá» ati ni òye.
  • Asá» itẹ rẹ gbá»dá» má» ki o si wa ni titodaadaa.
  • A gbá»dá» gba á» laaye lati lo ile iyagbẹ ki o si wẹ.

Awon ohun ohun elo ti ara – ilera, imototo ati itoju

  • Won ni lati beere lowo re ti o ba fe ba wa soro ni ibi koko pelu okan ninu awon osise abojuto nipa ohun to jomo eto ara ti o nii se pelu ilera, imototo ati ohun elo ti o nilo tabi ti o jo mo e nigba ti o ba wa ni atimole.
  • Olopa yo se eto lati pese ohun ti a lero pe o nilo lati ba aini re pade. Ti o ba fe, eni ti o ba e soro le je eya abo tabi ako bi tire.
  • Ti o ba je obirin ti o tii pe omo odun 18 (meji dilogun) tabi ti o ju bee lo, a ni lati beere lowo re ti o ba fe tabi ti o ba ma nilo awon ohun ti fi se nkan osu ni igba ti o ba wa ni atimole ati wi pe a ni lati so fun e pe:
    • gbogbo ohun elo ni a o pese fun o ni ofe -awon ohun ipaaro wa; ati -gbogbo ohun elo yii ni awon ebi re tabi ore re le pese fun o ni apo ara won ti awon osise abojuto wa ba fara mo o.
  • Ti o ba je obirin ti ko tii pe omo odun 18 (meji dilogun), osise abojuto maa seto wi pe eni ti o je obirin wa ni ago olopa lati toju re ati pe won yo beere ti o ba fe ohun elo ti ara ati ti nkan osu

Awon asá»

Bi a ba gba awá»n asá» rẹ kuro lá»wá» rẹ, awá»n á»lá»pa gbá»dá» pese asá» omiran fun á».

Ounjẹ ati ohun mimu

A gbá»dá» fun á» ni ounjẹ ẹmẹta (3) lojumá» pẹlu awá»n ohun mimu. O si tun le mu awá»n ohun mimu laarin ounje.

Eré Idaraya

Bi o ba seese o yẹ ki a gba Ỡlaaye nita lojoojumỠfun atẹgun.

Nigbati awá»n oá»lá»pa ba beere ibeere lá»wá» rẹ

  • Iyara naa ye ki o má»Ì , lá»wá»á»rá» ati ni òye.
  • O ko nilo lati dide duro.
  • O yẹ ki awá»n Ọlá»pa naa le sá» oruká» wá»n ati ipo wá»n fun á».
  • O yẹ ki o ni isinmi ni awá»n akoko ounjẹ ati isimi fun ohun mimu lẹyin wakati meji.
  • O yẹ ki a gba o laaye fun o kere ju isinmi wakati 8 ninu wakati 24 ti o fi wa ni atimá»le.

Awá»n ohun elo Igbagbá»

Sá» fun oá»lá»pa ti o ba nilo ohunkohun ti yoo ran á» lá»wá» lati se ẹsin rẹ nigbati o ba wa ni agá» á»lá»pa. Wá»n le pese iwe ẹsin ati awon nklan miiran , gẹgẹ bi o se fẹ.

Awá»n akoko ti awá»n ofin deede nyatá»

Gbigba agbẹjá»ro lati ran á» lá»wá»

Awá»n akanse akoko kan wa ti awá»n á»lá»pa nilo lati yara beere awon ibeere kan lá»wá» rẹ ki o to le ba agbẹjá»ro kan sá»rá».. Iwifun nipa awá»n akanse akoko wá»nyi ni a fihan ninu Awá»n Ise Ofin. Eyi nsá» ohun ti awá»n á»loá»pa lese tabi eyi ti wá»n kole se nigbati o ba wa ni agá» á»lá»pa. Bi o ba fẹ ye awá»n alaye naa wo, wá»n wa ni ipin á»rá» 6.6 ti Ofin C ti Awon Ise Ofin naa.

Akoko akanse kan wa ti awá»n á»lá»pa koni jẹki o sá»rá» pẹlu agbẹjá»ro ti o ti yan. Ti eyi ba sẹlẹ a gbá»dá» gba á» laaye lati yan agbẹjá»ro miiran. Bi o ba fẹ wo awá»n alaye naa, wá»n wa ni Afikun B ti Ofin C ti Awon Ise Ofin naa.

Sisá» fun ẹnikan wipe o wa ni agá» á»lá»pa

Awon akanse akoko kan wa ti awá»n á»lá»pa koni gba ki o kan si ẹnikẹni. Iwifun nipa awá»n akanse akoko wá»nyi wa ninu Awon Ise Ofin naa.

Bi o bafe wo ekunrere alaye naa, wá»n wa ni Afikun B ti Ofin C ti Awon Ise Ofin naa.

Awá»n ẹsẹ á»ti mimu ati ogun oloro mimu l’akoko iwaká»

Bi o ba wa l’agá» á»lá»pa nitori awá»n ẹsẹ á»ti mimu ati ogun oloro mimu l’akoko iwaká», o ni ẹtá» lati ba agbẹjá»ro sá»rá». Ẹtá» naa koni wipe o le ká» lati fun awá»n á»lá»pa ni eemi rẹ, ẹjẹ tabi itá» koda ti o ko ba tii ba agbẹjá»ro naa sá»rá».

Idani duro labe Ofin Ilera ti Iye 1983

Awá»n á»lá»pa naa tun le da á» duro ni agá» á»lá»pa fun ayẹwo labẹ Ofin Ilera Ọpá»lá» ti o ko bati pe á»má» á»dun mejidinlogun tabi ju bẹ lá» atipe nitori ewu pe ihuwasi rẹ o fa ijamba lile abi iku fun á» tabi fun ẹlomiran, o ko lero pe ki a da á» gunlẹ si ibo miran. Bi a bati da á» duro labẹ Ofin Ilera Ọpá»lá» eyi ko tumá» si wipe a ti mu á» fun ẹsẹ kankan.

Eyi tumá» si wipe awá»n á»lá»pa gbá»dá» s’eto fun á» lati ri dokita ati Aká»á¹£áº¹má»á¹£áº¹ Ilera Ọpá»lá» ti a fun l’asẹ lati se ayẹwo naa. A gbá»dá» yẹ o wo laarin wakati 24 ti o de agá» á»lá»pa, tabi ti a ti da á» duro si agá» á»lá»pa, sugbá»n awá»n á»lá»pa yá» gbiyanju lati s’eto yi ni kiakia. Ni agá» á»lá»pa, akoko idaduro oni wakati 24 fun ayẹwo le lá»gun fun wakati 12 si ti dokita ba ro pe o yẹ ti á»ga á»lá»pa naa si fá»wá» si. Ni akoko yii, awá»n á»lá»pa le gbe á» lo si ibi ti o yẹ kan lati jẹ ki ayẹwo naa seese.

Nigbati o ba nduro fun ayẹwo, awá»n á»lá»pa le s’eto fun á» lati ri Onisẹ Ilera ti a fun ni asẹ. Wá»n kole se ayẹwo naa, sugbá»n wá»n yo ran á» lá»wá» pẹlu awá»n ailera miiran ti o le ni ati ran á» lá»wá» lati s’alaye ohun ti idanwo naa tumo si.

Awá»n Alejo Ahamá» Olominira

Awá»n ara ilu kan wa ti a ngba laaye lati wá»le si agá» á»lá»pa lai sá»tẹlẹ. A npe wá»n ni alejo ahamá» olominira ti wá»n si nsiṣẹ naa l’atinuwa lati ri pe a ntá»ju awá»n ti timá»le daadaa ati lati le ni ẹtá» wá»n.

O ko ni ẹtá» lati ri awá»n alejo ahamá» olominira tabi beere pe ki wá» o bẹ á» wo sugbá»n alejá» kan le beere lati ri á». Bi alejo ahamá» olominira ba wa ki á» nigbati o wa ni ahamá» wá»n yo ma sisẹ l’ominira ara wá»n lati ri pe aabo wa fun itá»ju ati ẹtá» rẹ.

Ẹwẹ, o ko nilo lati ba wá»n sá»rá» bi o ko ba fẹ.

Bi o ti le se ifisun

Bi o ba fẹ se ẹsun nipa bi a se ntá»ju rẹ, beere lati ba á»lá»pa kan ti o jẹ oluyẹwo tabi á»ga sá»rá». Lẹyin ti a ti fi á» silẹ, o tun le ifisun ni agá» á»lá»pa yoowu, si Ọfiisi Ajá» fun Ihuwasi Ọlá»pa (IOPC) tabi nipasẹ agbẹjá»ro kan tabi MP to nduro fun á».